Aisaya 61:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní kí n máa kéde ọdún ojurere OLUWA,ati ọjọ́ ẹ̀san Ọlọrun wa;kí n sì máa tu àwọn tí ń ṣọ̀fọ̀ ninu.

Aisaya 61

Aisaya 61:1-11