Aisaya 56:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ẹ̀yin orílẹ̀-èdè láti òkèèrè, ẹ máa bọ̀,gbogbo yín ẹ máa bọ̀ bí ẹranko inú ìgbẹ́, ẹ wá jẹ àjẹrun.

Aisaya 56

Aisaya 56:8-12