Aisaya 53:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, n óo fún un ní ìpín,láàrin àwọn eniyan ńlá,yóo sì bá àwọn alágbára pín ìkógun,nítorí pé ó fi ẹ̀mí rẹ̀ lélẹ̀ fún ikú,wọ́n sì kà á mọ́ àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀.Sibẹsibẹ ó ru ẹ̀ṣẹ̀ ọpọlọpọ eniyan,ó sì bẹ̀bẹ̀ fún àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀.

Aisaya 53

Aisaya 53:5-12