Aisaya 52:10 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA yóo lo agbára mímọ́ rẹ̀, lójú àwọn orílẹ̀-èdè,gbogbo eniyan, títí dé òpin ayé, yóo sì rí ìgbàlà Ọlọrun wa.

Aisaya 52

Aisaya 52:3-15