Aisaya 51:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ wo Abrahamu baba yín,ati Sara tí ó bi yín.Òun nìkan ni nígbà tí mo pè é,tí mo súre fún un,tí mo sì sọ ọ́ di ọpọlọpọ eniyan.

Aisaya 51

Aisaya 51:1-11