Aisaya 51:15 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nítorí èmi ni OLUWA, Ọlọrun rẹ,ẹni tí ó rú òkun sókè,tí ìgbì rẹ̀ fi ń pariwo;OLUWA àwọn ọmọ ogun ni orúkọ mi.

Aisaya 51

Aisaya 51:6-21