Aisaya 51:13 BIBELI MIMỌ (BM)

O gbàgbé OLUWA ẹlẹ́dàá rẹ,tí ó ta ojú ọ̀run bí aṣọ,tí ó fi ìpìlẹ̀ ayé sọlẹ̀.O wá ń fi gbogbo ọjọ́ ayé bẹ̀rù ibinu àwọn aninilára,nítorí wọ́n múra tán láti pa ọ́ run?Ibinu àwọn aninilára kò ní dé ọ̀dọ̀ rẹ mọ́.

Aisaya 51

Aisaya 51:10-22