Aisaya 5:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ló tún kù tí ó yẹ kí n ṣe sí ọgbà àjàrà mi tí n kò ṣe?Ìgbà tí mo retí kí ó so èso dídùn,kí ló dé tí ó fi so èso kíkan?

Aisaya 5

Aisaya 5:1-8