Aisaya 5:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn óo hó lé Israẹli lórí lọ́jọ́ náàbí ìgbà tí omi òkun ń hó.Bí eniyan bá wọ ilẹ̀ náà yóo rí òkùnkùn ati ìnira.Ìkùukùu rẹ̀ yóo sì bo ìmọ́lẹ̀.

Aisaya 5

Aisaya 5:21-30