Aisaya 5:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó kọ́ ilẹ̀ rẹ̀, ó sì ṣa gbogbo òkúta ibẹ̀ kúrò.Ó gbin àjàrà dáradára sinu rẹ̀.Ó kọ́ ilé ìṣọ́ gíga sí ààrin rẹ̀,ó sì ṣe ibi tí wọn yóo ti máa fún ọtí sibẹ.Ó ń retí kí àjàrà rẹ̀ so,ṣugbọn èso kíkan ni ó so.

Aisaya 5

Aisaya 5:1-10