Aisaya 5:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn tí ń ṣe àfọwọ́fà ẹ̀ṣẹ̀ gbé!Àwọn tí wọn ń fi ìwà aiṣododo fa ẹ̀ṣẹ̀ bí ẹni tí ń fi okùn fa ẹṣin.

Aisaya 5

Aisaya 5:8-24