Aisaya 5:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà àwọn eniyan mi óo lọ sí oko ẹrú nítorí àìmòye wọn,ebi ni yóo pa àwọn ọlọ́lá wọn ní àpakú,òùngbẹ óo sì gbẹ ọpọlọpọ wọn.

Aisaya 5

Aisaya 5:11-16