Aisaya 48:6 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ ti fetí ara yín gbọ́,nítorí náà, ẹ wo gbogbo èyí, ṣé ẹ kò ní kéde rẹ̀?Láti àkókò yìí lọ, n óo mú kí ẹ máa gbọ́ nǹkan tuntun,àwọn nǹkan tí ó farapamọ́ tí ẹ kò mọ̀.

Aisaya 48

Aisaya 48:5-15