Aisaya 47:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni àwọn tí ẹ jọ ń ṣiṣẹ́ pọ̀ rí sí ọ,àwọn tí ẹ ti jọ ń ṣòwò pọ̀ láti ìgbà èwe rẹ.Olukuluku wọn ti ṣìnà lọ,kò sí ẹni tí yóo gbà ọ́ sílẹ̀.”

Aisaya 47

Aisaya 47:12-15