Aisaya 46:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Èmi náà ni, títí di ọjọ́ ogbó yín,n óo gbé yín títí tí ẹ óo fi hewú lórí.Èmi ni mo da yín, n óo sì máa tọ́jú yín,n óo máa gbé yín, n óo sì gbà yín là.

Aisaya 46

Aisaya 46:1-5