Aisaya 46:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn mejeeji jọ tẹríba, wọ́n jọ doríkodò,wọn ò lè gba àwọn ẹrù wọn kalẹ̀.Àwọn pàápàá yóo lọ sí ìgbèkùn.

Aisaya 46

Aisaya 46:1-6