Aisaya 43:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ mú àwọn eniyan mi jáde,àwọn tí wọ́n ní ojú, ṣugbọn tí ojú wọn ti fọ́,wọ́n ní etí, ṣugbọn etí wọn ti di.

Aisaya 43

Aisaya 43:1-9