Aisaya 43:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Má bẹ̀rù nítorí mo wà pẹlu rẹ,n óo kó àwọn ọmọ rẹ wá láti ìlà oòrùn,n óo sì ko yín jọ láti ìwọ̀ oòrùn.

Aisaya 43

Aisaya 43:1-9