Aisaya 43:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà mo sọ àwọn olórí ibi mímọ́ mi di aláìmọ́,mo fi Jakọbu sílẹ̀ fún ìparun;mo sì sọ Israẹli di ẹni ẹ̀sín.”

Aisaya 43

Aisaya 43:24-28