Aisaya 43:17 BIBELI MIMỌ (BM)

ẹni tí ó kó kẹ̀kẹ́ ogun ati ẹṣin jáde, ogun, ati àwọn ọmọ-ogun;wọ́n dùbúlẹ̀ wọn kò lè dìde mọ́,wọ́n kú bí iná fìtílà.

Aisaya 43

Aisaya 43:16-21