Aisaya 37:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo gbẹ́ kànga mo sì mu omi ninu wọn.Mo ti fi ẹsẹ̀ mi tẹ gbogbo omi odò kéékèèké ilẹ̀ Ijipti ní àtẹ̀gbẹ.’

Aisaya 37

Aisaya 37:17-29