Aisaya 36:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo wọn dákẹ́, kò sí ẹnìkan tí ó sọ nǹkankan nítorí ọba ti pàṣẹ pé ẹnikẹ́ni kò gbọdọ̀ dá a lóhùn.

Aisaya 36

Aisaya 36:17-22