Aisaya 35:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò ní sí kinniun níbẹ̀,bẹ́ẹ̀ ni ẹranko burúkú kankan kò ní gba ibẹ̀.A kò ní rí wọn níbẹ̀,àwọn tí a ti rà pada ni yóo gba ibẹ̀.

Aisaya 35

Aisaya 35:5-10