Aisaya 34:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí mo ti rẹkẹ idà mi lókè ọ̀run,yóo sọ̀kalẹ̀ láti ṣe ìdájọ́ àwọn ará Edomu;yóo sọ̀kalẹ̀ sórí àwọn tí mo fẹ́ parun.

Aisaya 34

Aisaya 34:3-12