Aisaya 34:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí OLUWA ń bínú sí gbogbo orílẹ̀-èdè,inú rẹ̀ sì ń ru sí àwọn eniyan ibẹ̀.Ó ti fi wọ́n sílẹ̀ fún ìparun, ó sì ti fà wọ́n kalẹ̀ fún pípa.

Aisaya 34

Aisaya 34:1-3