Aisaya 33:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣàánú wa OLUWA,ìwọ ni a dúró tí à ń wò.Máa ràn wá lọ́wọ́ lojoojumọ,sì máa jẹ́ olùgbàlà wa nígbà ìṣòro.

Aisaya 33

Aisaya 33:1-8