Aisaya 33:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ kò ní rí àwọn aláfojúdi náà mọ́,àwọn tí wọn ń fọ èdè tí kò ní ìtumọ̀ si yín,tí wọn ń kólòlò ní èdè tí ẹ kò gbọ́.

Aisaya 33

Aisaya 33:15-24