Aisaya 32:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Kìkì ibi ni èrò inú àwọn eniyankeniyan.Wọn a máa pète ìkà,láti fi irọ́ pa àwọn talaka run,kì báà jẹ́ pé ẹjọ́ aláìní jàre.

Aisaya 32

Aisaya 32:1-10