Aisaya 32:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Olukuluku yóo dàbí ibi ààbò nígbà tí ẹ̀fúùfù bá ń fẹ́ati ibi ìsásí nígbà tí ìjì bá ń jàWọ́n óo dàbí odò ninu aṣálẹ̀,ati bí ìbòòji àpáta ńlá nílẹ̀ olóoru.

Aisaya 32

Aisaya 32:1-6