Aisaya 31:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀rù yóo ba ọba Asiria, yóo sálọ.Ìpayà yóo mú kí àwọn ọ̀gágun rẹ̀ ju àsíá sílẹ̀.OLUWA ló sọ bẹ́ẹ̀,OLUWA tí iná rẹ̀ wà ní Sioni,tí ojú ààrò rẹ̀ wà ní Jerusalẹmu.

Aisaya 31

Aisaya 31:1-9