Aisaya 31:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni ó gbọ́n,ó sì mọ ọ̀nà tí ó fi lè mú kí àjálù dé bá eniyan,kì í sọ̀rọ̀ tán, kó yí ọ̀rọ̀ rẹ̀ pada.Ṣugbọn yóo dìde sí ìdílé àwọn aṣebi,ati àwọn tí ń ti àwọn oníṣẹ́ ẹ̀ṣẹ̀ lẹ́yìn.

Aisaya 31

Aisaya 31:1-9