Aisaya 30:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìbẹ̀rù-bojo yóo mú àwọn ará Asirianígbà tí wọ́n bá gbóhùn OLUWA,nígbà tí ó bá fi kùmọ̀ rẹ̀ lù wọ́n.

Aisaya 30

Aisaya 30:22-33