Aisaya 30:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ààbò Farao yóo di ìtìjú fún wọn,ibi ìpamọ́ abẹ́ Ijipti yóo di ìrẹ̀sílẹ̀ fún wọn.

Aisaya 30

Aisaya 30:1-10