Aisaya 30:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Omi yóo máa ṣàn jáde láti orí gbogbo òkè gíga ati gbogbo òkè ńlá, ní ọjọ́ tí ọpọlọpọ yóo kú, nígbà tí ilé ìṣọ́ bá wó lulẹ̀.

Aisaya 30

Aisaya 30:24-28