Aisaya 3:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀fọ̀ ati ẹkún yóo pọ̀ ní ẹnu ibodè Jerusalẹmu.Yóo dàbí obinrin tí wọ́n tú sí ìhòòhò,tí ó jókòó ní ilẹ̀ẹ́lẹ̀.

Aisaya 3

Aisaya 3:20-26