Aisaya 3:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Òórùn burúkú yóo wà dípò òórùn dídùn ìpara,okùn yóo wà dípò ọ̀já;orí pípá yóo dípò irun tí wọ́n ṣe lọ́ṣọ̀ọ́,aṣọ ọ̀fọ̀ yóo dípò aṣọ olówó iyebíye.Ìtìjú yóo bò yín dípò ẹwà.

Aisaya 3

Aisaya 3:20-26