Aisaya 29:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Lójijì, kíá,OLUWA àwọn ọmọ ogun yóo dé ba yín,pẹlu ààrá, ati ìdágìrì, ati ariwo ńlá;ati ààjà, ati ìjì líle,ati ahọ́n iná ajónirun.

Aisaya 29

Aisaya 29:5-10