Aisaya 29:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Sibẹsibẹ n óo mú ìpọ́njú bá ìlú tí ń jẹ́ pẹpẹ Ọlọrun.Ìkérora ati ìpohùnréré ẹkún yóo wà ninu rẹ̀,bíi Arieli ni yóo sì rí sí mi.

Aisaya 29

Aisaya 29:1-4