Ṣé OLUWA ti jẹ wọ́n níyà bí ó ti fìyà jẹ àwọn tí ó jẹ wọ́n níyà?Ṣé ó ti pa wọ́n bí ó ti pa àwọn tí ó pa wọ́n?