Aisaya 27:3 BIBELI MIMỌ (BM)

“Èmi OLUWA ni olùṣọ́ rẹ̀,lásìkò, lásìkò ni mò ń bomi rin ín;tọ̀sán-tòru ni mò ń ṣọ́ ọkí ẹnìkan má baà bà á jẹ́.

Aisaya 27

Aisaya 27:1-7