Aisaya 27:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ náà,a óo fun fèrè ogun ńlá,àwọn tí ó ti sọnù sí ilẹ̀ Asiriaati àwọn tí a lé lọ sí ilẹ̀ Ijiptiyóo wá sin OLUWA lórí òkè mímọ́ ní Jerusalẹmu.

Aisaya 27

Aisaya 27:4-13