Aisaya 27:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ẹ̀ka igi náà yóo dánígbà tí wọ́n bá gbẹ,àwọn obinrin yóo sì fi wọ́n dáná.Nítorí òye kò yé àwọn eniyan wọnyi rárá;nítorí náà, ẹni tí ó dá wọn kò ní ṣàánú wọn,Ẹni tí ó mọ wọ́n kò ní yọ́nú sí wọn.

Aisaya 27

Aisaya 27:5-13