Aisaya 27:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ náà,OLUWA yóo fi idà rẹ̀ tí ó mú, tí ó tóbi, tí ó sì lágbára,pa Lefiatani, ejò tí ó ń fò,Lefiatani, ejò tí ń lọ́ wérékéké,yóo sì pa ejò ńlá tí ń bẹ ninu òkun.

Aisaya 27

Aisaya 27:1-2