Aisaya 26:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò náà,orin tí wọn óo máa kọ ní ilẹ̀ Juda ni pé:“A ní ìlú tí ó lágbára,ó fi ìgbàlà ṣe odi ati ibi ààbò.

Aisaya 26

Aisaya 26:1-4