Aisaya 24:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn tí ń gbé inú ayé ti ba ilé ayé jẹ́,nítorí pé wọ́n ti rú àwọn òfinwọ́n ti tàpá sí àwọn ìlànàwọ́n sì da majẹmu ayérayé.

Aisaya 24

Aisaya 24:1-15