Aisaya 23:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ dákẹ́ jẹ́ẹ́, ẹ̀yin tí ń gbé etí òkun,ẹ̀yin oníṣòwò ará Sidoni;àwọn iranṣẹ yín ti kọjá sí òdìkejì òkun,

Aisaya 23

Aisaya 23:1-10