Aisaya 23:11 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ti na ọwọ́ rẹ̀ sórí òkunÓ ti mi àwọn orílẹ̀-èdè jìgìjìgì.Ó ti pàṣẹ nípa ilẹ̀ Kenaanipé kí wọ́n pa gbogbo ibi ààbò rẹ̀ run.

Aisaya 23

Aisaya 23:9-14