Aisaya 22:24 BIBELI MIMỌ (BM)

“Gbogbo ẹbí rẹ̀ ní agboolé baba rẹ̀ yóo di ẹrú rẹ̀, ati àwọn ọmọ ati àwọn ohun èlò, láti orí ife ìmumi, títí kan ìgò ọtí.”

Aisaya 22

Aisaya 22:18-25