Aisaya 22:2 BIBELI MIMỌ (BM)

ẹ̀yin tí ìlú yín kún fún ariwo, tí ẹ jẹ́ kìkì ìrúkèrúdò ati àríyá?Gbogbo àwọn tí ó kú ninu yín kò kú ikú idà,bẹ́ẹ̀ ni wọn kò kú lójú ogun.

Aisaya 22

Aisaya 22:1-4