Aisaya 22:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ ka iye ilé tí ó wà ní Jerusalẹmu, ẹ sì wó àwọn kan palẹ̀ ninu wọn, kí ẹ lè rí òkúta tún odi ìlú ṣe.

Aisaya 22

Aisaya 22:6-12